Igbẹjọ lori iku obinrin agbẹjọro to padanu ẹmi rẹ lọjọ keresimesi ọdun to kọja, Bolanle Raheem tẹsiwaju ni ileẹjọ lọjọru, ọjọ kẹdogun, oṣu kinni ọdun 2023. Ẹlẹri keji to jẹ akẹgbẹ afurasi olujẹjọ nidi ...